Logo Passei Direto
Buscar
Material
páginas com resultados encontrados.
páginas com resultados encontrados.

Prévia do material em texto

Owonrin Meji
Ase wonran woran lowo nile aye
Ase wonran woran ni ire gbogbo
Adia fun Orunmila
Ifa yoje olugbala fun omo araye
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje ifa gbamo moke mogba
En español:
La persona ridícula se convierte próspera en la tierra.
La persona con comportamiento ridículo tiene todas las cosas buenas.
Adivinaron Ifá para Orunmila.
Ifá tendrá el título de liberador del mundo.
Él fue aconsejado ofrecer sacrificio.
Él cumplió.
Por eso, Ifá, rescátame, te grité para que me rescates.
Òkànràn-Òtúrúpòn
Ifá kíkọ ní í múni mọ Ifá
Ònà ṣíṣì ní í múni mọ ònà
Ònà tí a kò rìn rí
Ní í ṣe ènìyàn ní ṣíbálá ṣíbóló.
A dífá fún Ọ̀rúnmìlà
A kì fún Òsányìn Ewèlè
Lọ́jọ́ tí Olódùmarè dé igbá kalẹ̀
Tí Ọ̀rúnmìlà ní òun lè kí Ifá
Kí òun mọ ohun tí ń bẹ
Nínú igbá tí Olódùmarè dé kalẹ̀
Tí Òsányìn ń ké pé
Dàndàn kí ìdàn n ti 'dàn.
Ibí tí Ọ̀rúnmìlà bá yún,
Ibẹ̀ ni òun Òsányìn ń rè
Àfí kí Ewèlè tẹ̀ lé Ọ̀rúnmìlà.
Ifá ń ké pé òde kò dára
Ènìyàn tí a wí fún kó gbọ́
Kí á sọ̀rọ̀ fún un, kí á gbà.
Awíìgbọ́, Afọ́ọ̀gbà.
Ọjọ́ kìíní
Ló sọ Òsányìn di ẹrú Ifá.
Traducción al español:
Aprender Ifá nos hace comprender Ifá
Caminos abiertos nos hacen entender el camino
Caminos que nunca fueron transitados antes
Llevan a las personas a tropezar y caer.
Ifá fue consultado para Ọ̀rúnmìlà
Y fue saludado para Òsányìn Ewèlè
El día en que Olódùmarè trajo la calabaza a la Tierra
Y Ọ̀rúnmìlà dijo que saludaría a Ifá
Para entender lo que había dentro de ella.
En la calabaza que Olódùmarè trajo a la Tierra,
Òsányìn empezó a clamar, diciendo:
"Es necesario que el secreto del misterio sea revelado."
Dondequiera que Ọ̀rúnmìlà iba,
Allí Òsányìn lo seguía.
Incluso Ewèlè siguió a Ọ̀rúnmìlà.
Ifá clamaba, diciendo que el mundo no estaba en orden.
A quien se le da un aviso debe escucharlo,
Y a quien se le da un consejo debe aceptarlo.
Aquel que escucha consejos y acepta orientación.
El primer día,
Òsányìn fue hecho sirviente de Ifá.
Ogunda fun
Gburùú ònà níí dâ ejò lónà
Gburùú ònà níí dá ejò léyìn
A dífá fún Ògún
Ti hún lo rèé dá won ní ibi ti ó gbé fún
Ògún wo à ni?
Ògún tó dá won ní ibi ti ó gbé fún ni.
Traduccion:
El camino que no es liso es el que puede romper el Tomo de la serpiente
Lanza adivinación para Ogun que iba a rescatar a la gente
Donde había problemas
Qué Ogun rescató a la gente donde había un problema?
EI Ogun se llama Ogundafun

Mais conteúdos dessa disciplina